Yorùbá

ÌFẸ́

Ohun tó ṣe pàtàkì jù lọ
  ni ìfẹ́ Mi sí ọ.
Ó dà bí òjò
  bí ó ṣe ń wẹ gbogbo
  ohun tí ó bá rọ̀ lé mọ́.
Ó dà bí oòrùn
  bí ó ṣe ń fún gbogbo
  ohun alààyè ní ìtura.
Ó dà bí afẹ́fẹ́
  bí ó ṣe ń fún gbogbo ohun
  tí ó nílò oúnjẹ rẹ̀ ní ìyè.

Bí èyí bá jẹ́ ìwà ìfẹ́,
  ǹjẹ́ gba àwọn àǹfààní rẹ̀.
Gba àwọn ìbùkún ìfẹ́
  sì pín àwọn èso rẹ̀
  pẹ̀lú àwọn tí o bá pàdé ní ọ̀nà rẹ.

Àṣàrò Tó Kàn

Àtòjọ Àkóónú